Ki is̩e o̩ranyan lati mã fi ami sori gbogbo o̩ro̩ ninu iwe Yoruba afi bi o ba je̩ iwe ti a ko̩ pataki fun awo̩n o̩mo̩de ti koi mo̩ iwe ika tabi awo̩n ajeji. Itumo̩ ati fifi o̩kan te̩le ohun ti a nka to lati dari e̩ni ti nkawe nã ki o le mo̩ bi a ti ipe oniruru o̩ro̩ inu iwe nã. Ninu “Itumo̩ Ede Yoruba“ yi gbogbo o̩ro̩ ti a tumo̩ ni a fi ami si lori ge̩ge̩bi o ti ye̩ s̩ugbo̩n nibomiran kiki ibi ti a ro pe alaifi ami si i ie mu iruju tabi ipekupe wa li a fi ami si.
***
A so̩ oniruru o̩ro̩ ti a ri ninu awo̩n iwe ti a ye̩wo li oruko̩ ge̩ge̩bi ihuwasi wo̩n. A ni ireti pe li aipe̩ aoko̩ O̩gbo̩n — grama Ede Yoruba ni kikun, kiki ohun die̩ pataki ni a le to̩ka si ninu iwe yi. Ni kukuru, awo̩n o̩ro̩ ti ihuwasi wo̩n do̩gba ni a so̩ li oruko̩ kanna. Oruko̩ mo̩kanla li a fi so̩ awo̩n o̩ro̩ inu ede Yoruba.
Алфавит
Aa, (Ai ai), (Au au), Bb, Dd, Ee, E̩e̩, Ff, Gg, (Gb gb), Hh, Ii, Jj, Kk, Ll, Mm, Nn, Oo, O̩o̩, (Oi oi), Pp, Rr, Ss, S̩s̩, Tt, Uu, Ww, Yy.
Имеются дополнительные буквы e̩, o̩, s̩ (в некоторых изданиях они передаются как ẹ, ọ, ṣ или e̱, o̱, š). Над гласными употребляются диакритические знаки: (´), (`), (˜). В алфавите отсутствуют буквы c, q, v, x, z.
Язык йоруба распространён в Западной Нигерии; на нём говорит 5,2 млн. человек.
Принадлежит к гвинейской группе суданских языков.